The Iwo Anthem which could also be referred to ‘Odidere Anthem’ is one of the symbols of Iwo people. Therefore, you can’t be from this beautiful land and don’t know the Anthem. See it below
IWO ANTHEM
Iwo o olodo oba
Ni’le odidere o
Okan saa niwa e gba o
Ire Iwo la n fe o
Ire Iwo la n fe o
Ewa omo Iwo o
Ewa ara ore wa
E je ka gbe’wo goke
Ire Iwo la n fe o
Ire Iwo la n fe o
N’ile ni loko lodo
Gbogbo aye ewa o
E je ka gbe’wo goke
Ire Iwo la n fe o
Ire Iwo la n fe o
Pledge (Ileri)
Mo se ileri fun Iwo Olodo Oba,
N’ile Odidere eye ire,
Pe lagbara Olodumare,
Iwo ko ni i t’oju mi baje,
Gbogbo ohun ti mo ba nilaye,
t’ile Odidere niwon nse,
emi ko je gbagbe Iwo Olodo oba,
ki Olorun ko ranmi lowo